Yoruba Hymns

OLUWA mbo; ayé o mi,

OLUWA mbo; ayé o mi, Oke y’o sidi n’ipo won, At’ irawo oju orun, Y’o mu imole won kuro. Oluwa mbo; bakan naa ko, Bi o ti wa n’irele ri; odo-aguntan ti a pa, eni-iya ti o si ku. Oluwa mbo; ni eru nla, L’owo ina...

READ MORE

Baba, a tun pade l’oko Jesu

Baba, a tun pade l’oko Jesu A si wa teriba lab’ese Re A tun fe gb‘ohun wa soke si O Lati Wa anu, lati korin ‘yin. Ayin O fun itoju ‘gbagbogbo, Ojojumo l‘ao ma rohin ‘sc re; Wiwa laye wa, anu Re ha ko? Apa Re ki 0 fi ngba ni...

READ MORE

Nigba kan ni Betlehemu

Nigba kan ni Betlehemu Ile kekere kan wa Nib’i’ya kan te mo’re si Lori ibuje eran Maria n’iya omo na Jesu Kristi l’omo na O t’orun wa s’ode aye On l’Olorun Oluwa O f’ile eran se ile...

READ MORE

B’olorun Oba orun

B’olorun Oba orun Ti ma nsoro n’igba ni; Otun ba wa soro be loni Arakunrin, oto ni Ohun t’Oba wi fun o; Ohun kan l’aigbodo-mase;gboran. CHORUS Sa gboran, sa gboran; Eyi ni ‘fe Re “Gbat’O ba ranse si o...

READ MORE

WA s’adura oorọ,

WA s’adura oorọ, Kunlẹ k’a gbadura; Adura ni ọpa Kristiani, Lati b’Ọlọrun rin. Lọsan, wolẹ labẹ, Apat’ ayeraye;  Itura ojiji Rẹ dun, Nigba t’orun ba mu. Jẹ ki gbogbo ile, Wa gbadura l’alẹ; Ki ile wa di...

READ MORE

BABA mi gbọ temi!

BABA mi gbọ temi! ‘Wọ ni Alabo mi, Ma sunmọ mi titi; Oninure julọ! Jesu Oluwa mi, Iye at’ogo mi, K’igba naa yara de, Ti n ó de ọdọ Rẹ.           Olutunu julọ, ‘Wọ ti n gbe inu...

READ MORE

N’nu gbogbo ayida aye

N’nu gbogbo ayida aye, Ayo on wahala; Iyin Olorun ni y’o ma Wa l’enu mi titi. Gbe Oluwa ga pelu mi, Ba mi gb’Oko Re ga; N’nu wahala, ‘gba mo kepe, O si yo mi kuro Ogun Olorun wa yika Ibugbe oloto; Eniti o ba...

READ MORE

Baba, Eleda wa,

Baba, Eleda wa, Gbo orin iyin wa L’aiye ati l’orun, Baba Olubukun: Iwo l’ogo ati iyin, Ope, ati ola ye fun. ‘Wo Olorun Omo, T’O ku lati gba wa; Enit’O ji dide, Ti O goke lo; Iwo l’ogo, ati iyin, Ope, ati ola ye fun. Si O Emi Mimo, Ni a korin...

READ MORE
Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria