Bi Krist’ti da okan ni nde

Share If You Love!

Bi Krist’ti da okan ni nde
Aye mi ti dabi orun,
Larin ‘banuje at’aro
Ayo ni lati mo Jesu,

Aleluya! Ayo l’o je

Pe, mo ti ri ‘dariji gba.
Ibikibi ti mo ba wa
Ko s’ewu, Jesu wa nibe.

Moti ro pe orun jinna

Sugbon nigbati Jesu de
L’orun ti de ‘nu okan mi,
Nibe ni y’o si wa titi.

Nibo l’a le gbe I’aye

L’o r’oke tabi petele
L’ahere tabi agbala,
Ko s’ewu, Jesu wa nibe.

AMIN

Share If You Love!

Add Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria