Author page: Sam

WA s’adura oorọ,

WA s’adura oorọ, Kunlẹ k’a gbadura; Adura ni ọpa Kristiani, Lati b’Ọlọrun rin. Lọsan, wolẹ labẹ, Apat’ ayeraye;  Itura ojiji Rẹ dun, Nigba t’orun ba mu. Jẹ ki gbogbo ile, Wa gbadura l’alẹ; Ki ile wa di...

READ MORE

BABA mi gbọ temi!

BABA mi gbọ temi! ‘Wọ ni Alabo mi, Ma sunmọ mi titi; Oninure julọ! Jesu Oluwa mi, Iye at’ogo mi, K’igba naa yara de, Ti n ó de ọdọ Rẹ.           Olutunu julọ, ‘Wọ ti n gbe inu...

READ MORE

N’nu gbogbo ayida aye

N’nu gbogbo ayida aye, Ayo on wahala; Iyin Olorun ni y’o ma Wa l’enu mi titi. Gbe Oluwa ga pelu mi, Ba mi gb’Oko Re ga; N’nu wahala, ‘gba mo kepe, O si yo mi kuro Ogun Olorun wa yika Ibugbe oloto; Eniti o ba...

READ MORE

Baba, Eleda wa,

Baba, Eleda wa, Gbo orin iyin wa L’aiye ati l’orun, Baba Olubukun: Iwo l’ogo ati iyin, Ope, ati ola ye fun. ‘Wo Olorun Omo, T’O ku lati gba wa; Enit’O ji dide, Ti O goke lo; Iwo l’ogo, ati iyin, Ope, ati ola ye fun. Si O Emi Mimo, Ni a korin...

READ MORE

MO fi gbogbo re fun Jesu

MO fi gbogbo re fun Jesu, Patapata l’aiku kan, Ngó ma fe, ngó si gbekele, Ngó wa lodo re titi. CHORUS Mo fi gbogbo re (2ce) Fun o, Olugbala mi, ni Mo fi won sile. Mo fi gbogbo re fun Jesu, Mo fi rele wole fun; Mo fi gbadun ayé sile; Gbami...

READ MORE

Kii se l’ainireti,

Kii se l’ainireti, Ni mo to wa; Kii se l’aini ‘gbagbo, Ni mo kunle; Ese ti gori mi, Eyi sa l’ebe mi, Eyi sa l’ebe mi Jesu ti ku. A! ese mi po ju, O pon koko Adale, adale, Ni mo n d’ese    Ese aiferan...

READ MORE

Apata ayeraye

Apata ayeraye Se ibi isadi mi; Je ki omi oun eje, T’o n san lati iha Re, Se iwosan f’ese mi, K’o si so mi di mimo. K’ Ise ise owo mi, Lo le mu ofin Re se; B’ itara mi ko l’are, T’ omije mi n san titi; Won...

READ MORE

MA gesin lo l’ola nla Re;

MA gesin lo l’ola nla Re; Gbo gbogb’ayé, n ke “Hosanna” Olugbala, ma lo pele, Lori im’ope at’aso. Ma gesin lo l’ola nla Re; Ma f’irele gesin lo ku; Kristi, segun Re bere na; Lori ese ati iku. Ma gesin lo...

READ MORE

ORE-OFE! ohun

ORE-OFE! ohun Adun ni l’eti  wa, Gbohun-gbohun re  y’o gba orun kan, Ayé o gbe pelu.           Ore-ofe sa, N’igbekele mi; Jesu ku fun arayé, O ku fun mi pelu. Ore-ofe...

READ MORE
Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria