Monthly Archives: October 2015

IRAPADA ITAN IYANU

IRAPADA ITAN IYANU 1. Irapada ! itan iyanu Ihin ayo fun gbogbo wa Jesu ti ra ‘dariji fun wa O san ‘gbese na lor’igi A ! elese gba ihin na gbo Jo gba ihin oto na gbo Gbeke re le Olugbala re T’O mu igbala fun o wa 2. O mu wa t’inu ‘ku bo

READ MORE

Ha! Egbe mi, e w’ asia

Ha! Egbe mi, e w’ asia 1. Ha! Egbe mi, e w’ asia Bi ti nfe lele! Ogun ‘ranwo sunmo tosi, A fere segun! D’odi mu, Emi fere de Beni Jesu nwi, Ran ‘dahun pada s’ orun pe, Awa o dimu! 2. Wo opo ogun ti mbowa, Esu nko won bo; Awon alagbara nsubu, A...

READ MORE

Gba aye mi, Oluwa

Gba aye mi, Oluwa 1. Gba aye mi, Oluwa Mo ya si mimo fun O Gba gbogbo akoko mi Ki won kun fun iyin re 2. Gba owo mi ko si je Ki n ma lo fun ife Re Gba ese mi ko si je Ki won ma sare fun O 3. Gba ohun mi

READ MORE

AYE SI MBE NILE OD’AGUTAN

AYE SI MBE NILE OD’AGUTAN 1. Aye si mbe nile Od’agutan Ewa ogo re npe o pe « ma bo » Wole, wole, wole nisisiyi 2. Ojo lo tan, orun si fere wo Okunkun de tan, ‘mole nkoja lo Wole, wole, wole nisisiyi 3. Ile iyawo na kun fun ase Wole, wole to oko...

READ MORE
Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria