Monthly Archives: September 2015

MIMO, MIMO, MIMO, OLODUMARE

MIMO, MIMO, MIMO, OLODUMARE1. Mimo, mimo,mimo, OlodumareNi kutukutu n’iwo O gbo orin waMimo, mimo, mimo ! Oniyonu juloOlogo meta, lae Olubukun 2. Mimo, mimo, mimo ! awon t’orun nyinWon nfi ade wura won le ‘le yi ‘te kaKerubim, serafim nwole...

READ MORE

Okan mi yin Oba orun

Okan mi yin Oba orun 1. Okan mi yin Oba orunMu ore wa sodo re‘Wo ta wosan, t’a darijiTal’aba ha yin bi Re ?Yin Oluwa, yin OluwaYin Oba ainipekun 2. Yin fun anu t’o ti fi hanF’awon Baba ‘nu ponjuYin L Okan na ni titiO lora lati binuYin Oluwa, yin...

READ MORE

FI IYIN FUN JESU OLURAPADA WA

FI IYIN FUN JESU OLURAPADA WA 1. Fi iyin fun Jesu, Olurapada wa,Ki aye k’okiki ife Re nla ;Fi iyin fun ! eyin Angeli ologo,F’ola at’ogo fun oruko re,B’olu’agutan, Jesu y’o to omo ReL’apa Re l’o ngbe won le l’ojojoEyin eniyan mimo ti ngb’oke...

READ MORE

WA BA MI GBE

WA BA MI GBE1. Wa ba mi gbe, ale fere le tanOkunkun nsu, Oluwa ba mi gbe;Bi oluranlowo miran ba yeIranwo alaini, wa ba mi gbe 2. Ojo aye mi nsare lo s’opinAyo aye nku, ogo re nwomiAyida at’ibaje ni mo n ri‘wo ti ki yipada, wa ba mi gbe 3. Ma wa...

READ MORE
Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria