Monthly Archives: May 2015

L’owuro Ojo Ajinde

L’owuro Ojo Ajinde L’owuro ojo ajinde,T’ara t’okan y’o pade,Ekun, ’kanu on iroraY’o dopin. Nihin won ko le sai pinyaKi ara ba le sinmi,K’o si fi idakeroroSun fonfon. Fun ’gba die ara are yiL’a gbe s’ibi ’simi re;Titi di imole oroAjinde. Okan to...

READ MORE

Jesu Ye Titi Aye

1. JESU ye: titi aye,Eru iku ko ba mi mo;Jesu ye: lat’ oni loIsa oku ko nipa moAlleluya! 2. Jesu ye: NitorinaIku je ona si iye;Eyi y’oje ‘tunu wa,‘Gbat’ akoko iku ba deAlleluya! 3. Jesu ye: fun wa l’O kuNje tire ni a o maa se;A o f’okan funfun...

READ MORE

JERUSALEM T’ORUN

JERUSALEM T’ORUN 1. Jerusalem t’orun L’orin mi, ilu mi  Ile mi bi mba ku Ekun Ibukun mi Ibi ayo  Nigbawo ni Nr’oju Re Olorun mi? 2. Nibe l’Oba mi wa T’ada lebi laye Angeli nkorin fun Won si nteriba...

READ MORE
Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria