Monthly Archives: March 2015

Oluwa mi mo njade lo

Oluwa mi mo njade lo 1. Oluwa mi mo njade lo Lati se ise ojo mi Iwo nikan l’ emi o mo L’oro l’ ero, ati n’ ise 2. Ise t’o yan mi l’ anu re Je ki nle se tayotayo Ki nr’ oju Re ni ise mi K’ emi si le...

READ MORE

L’ oju ale gbat’ orun wo

L’ oju ale gbat’ orun wo 1. L’ oju ale gbat’ orun wo Nwon gbe abirun w’ odo Re Oniruru ni aisan won Sugbon nwon f’ ayo lo ‘le won 2. Jesu a de l’ oj’ ale yi A sunmo t’ awa t’ arun wa Bi a ko tile le ri O Sugbon a mo

READ MORE

K’a to sun Olugbala wa

K’a to sun Olugbala wa 1. K’a to sun Olugbala wa Fun wa n’ ibukun ale A jewo ese wa fun O Iwo l’o le gba wa la 2. B’ ile tile ti sududu Okun ko le se wa mo Iwo eniti ki sare Nso awon enia Re 3. B’ iparun tile yi wa ka

READ MORE

Onigbagbo e bu sayo!

Onigbagbo e bu sayo! 1. Onigbagbo e bu sayo!Ojo nla loni fun waKorun fayo korin kikan,Kigbo atodan gberin E ho! E yo! Okun atodo gbogbo. 2. E jumo yo, gbogbo eda,Laye yi ati lorun,Ki gbogbo ohun alaayeNile, loke, yin JesuE fogo funOba nla ta bi...

READ MORE

Ojo nla l’ ojo ti mo yan

Ojo nla l’ ojo ti mo yan 1. Ojo nla l’ ojo ti mo yan Olugbala l’ Olorun mi; Oye ki okan mi ma yo, K’o si ro ihin na ka ‘le. Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki nma gbadura Ki nma sora ki nsi ma

READ MORE

Enikan nbe to feran wa

Enikan nbe to feran wa Enikan nbe to feran waA! O fe wa!Ife Re ju t’iyekan loA! O fe wa!Ore aye nko wa sileBoni dun, ola le koroSugbon Ore yi ki ntan niA! O fe wa! Iye ni fun wa ba ba moA! O fe wa!Ro, ba ti je ni gbese toA! O fe wa!Eje

READ MORE

B’ORUKO JESU TI DUN TO

B’ORUKO JESU TI DUN TO 1. B’oruko Jesu ti dun to, ogo ni fun Oruko Re o tan banuje at’ogbe ogo ni fun oruko Re ogo f’oko Re, ogo f’oko Re ogo f’oruko Oluwa ogo f’oko Re, ogo f’oko Re ogo f’oruko Oluwa 2. O wo okan to gb’ogbe san Ogo ni fun oruko...

READ MORE

IRAPADA ITAN IYANU

IRAPADA ITAN IYANU 1. Irapada ! itan iyanu Ihin ayo fun gbogbo wa Jesu ti ra ‘dariji fun wa O san ‘gbese na lor’igi A ! elese gba ihin na gbo Jo gba ihin oto na gbo Gbeke re le Olugbala re T’O mu igbala fun o wa 2. O mu wa t’inu ‘ku bo

READ MORE

OKAN MI NYO NINU OLUWA

OKAN MI NYO NINU OLUWA 1. Okan mi nyo ninu Oluwa ‘Tori O je iye fun mi Ohun Re dun pupo lati gbo Adun ni lati r’oju Re Emi nyo ninu Re Emi nyo ninu Re Gba gbogbo lo fayo kun okan mi ‘Tori emi nyo n’nu Re. 2. O ti pe t’O ti nwa

READ MORE

E JE J’A F’INU DIDUN

E JE J’A F’INU DIDUN 1. Eje k’a f’inu didun Yin Oluwa Olore Anu Re O wa titi Lododo dajudaju 2. On nipa agbara Re F’imole s’aye titun 3. O mbo gbogb’eda ‘laye O npese fun aini won 4. O bukun ayanfe Re Li aginju iparun 5. E je k’a f’inu didun Yin...

READ MORE

KO SU WA LATI MA KO ORIN TI IGBANI

KO SU WA LATI MA KO ORIN TI IGBANI 1. Ko su wa lati ma ko orin ti igbani Ogo f’olorun Aleluya A le fi igbagbo korin na s’oke kikan Ogo f’olorun, Aleluya! Omo olorun ni eto lati ma bu s’ayo Pe ona yi nye wa si, Okan wa ns’aferi Re Nigb’o se a o...

READ MORE

E WOLE F’OBA, OLOGO JULO

E WOLE F’OBA, OLOGO JULO 1. E wole f’oba, Ologo julo E korin ipa ati ife Re Alabo wa ni at’eni igbani O ngbe ‘nu ogo, Eleru ni iyin 2. E so t’ipa Re, e so t’ore Re ‘mole l’aso Re, gobi Re orun Ara ti nsan ni keke ‘binu Re je Ipa ona Re

READ MORE
Phone: +2348093415875
Fax: +2348135291769
S. O. S. Int’l. P. O. Box 1297
Agege, Lagos, Nigeria